Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Uzzi: 5. An overseer of the Levites

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 5. An overseer of the Levites

  1. Olórí òṣìṣẹ́ àwọn ọmọ Lefi ní Jerusalẹmu ní Ussi ọmọ Bani, ọmọ Haṣabiah, ọmọ Mattaniah ọmọ Mika. Ussi jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìran Asafu tí wọ́n jẹ́ akọrin ojúṣe nínú ìjọ́sìn ní ilé Ọlọ́run.