Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Urim and Thummim: Eleazar to ask counsel for Joshua, after the judgment of
Àwọn ẹsẹ nípa Eleazar to ask counsel for Joshua, after the judgment of
Kí ó dúró níwájú Eleasari àlùfáà, tí yóò gba ìpinnu fún láti béèrè Urimu níwájú Olúwa. Gẹ́gẹ́ bí òfin yìí ni òun pẹ̀lú gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli yóò jáde lọ, pẹ̀lú òfin rẹ̀ sì ni wọn ó wọlé.”