Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Uprightness: Reprove those who deviate from

1 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Reprove those who deviate from

  1. Nígbà tí mo rí i pé wọn kò rìn déédé gẹ́gẹ́ bí òtítọ́ ìyìnrere, mo wí fún Peteru níwájú gbogbo wọn pé, “Bí ìwọ, tí ì ṣe Júù ba ń rìn gẹ́gẹ́ bí ìwà àwọn kèfèrí, èéṣe tí ìwọ fi ń fi agbára mu àwọn kèfèrí láti máa rìn bí àwọn Júù?