Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Red Heifer: Blood of, sprinkled seven times before the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Blood of, sprinkled seven times before the tabernacle
Nígbà náà ni Eleasari àlùfáà yóò mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sórí ìka ọwọ́ rẹ̀ yóò sì wọn lẹ́ẹ̀méje ní ọ̀kánkán iwájú àgọ́ ìpàdé.