Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Pomegranate Tree: God's favour exhibited, in making fruitful
Àwọn ẹsẹ nípa God's favour exhibited, in making fruitful
Ǹjẹ́ èso ha wà nínú abà bí? Títí di àkókò yìí, àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ àti pomegiranate, àti igi olifi kò ì tí ì so èso kankan. “ ‘Láti òní lọ ni èmi yóò bùkún fún un yin.’ ”