Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tapestry: General references 2 ẹsẹ · 5 abala Wá "Tapestry" Gbogbo 47 Of the tabernacle 41 General references 2 In palaces 2 Gold thread woven in 1 In groves 1 Àwọn ẹsẹ nípa General references Òwe 7:16Mo ti tẹ́ ibùsùn mi pẹ̀lú aṣọ aláràbarà láti ilẹ̀ Ejibiti.Òwe 31:22Ó ṣe aṣọ títẹ́ fún ibùsùn rẹ̀; ẹ̀wù dáradára àti elése àlùkò ni aṣọ rẹ̀.