Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tact: General references 2 ẹsẹ · 11 abala Wá "Tact" Gbogbo 84 Joab's trick in obtaining David's consent to the return of Absalom 22 Nabal's wife 20 The town clerk of Ephesus 7 The wise woman of Abel 7 Of Saul, in managing malcontents 6 The church council at Jerusalem 6 In preaching 5 Solomon, in arbitrating between the harlots 5 Of Gideon 3 General references 2 Mordecai, in concealing Esther's nationality 1 Àwọn ẹsẹ nípa General references Òwe 15:1Ìdáhùn pẹ̀lẹ́ yí ìbínú padà ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ líle máa ń ru ìbínú sókè.Òwe 25:15Nípa sùúrù a lè yí ọba lọ́kàn padà ahọ́n tí ń sọ̀rọ̀ rírọ̀ sí egungun.