Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tabeel: 1. A Persian official in Samaria
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A Persian official in Samaria
Àti ní àkókò ìjọba Artasasta ọba Persia, Biṣilami, Mitredati, Tabeli àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ yòókù kọ̀wé sí Artasasta. A kọ ìwé náà ní ìlànà ìkọ̀wé Aramaiki èdè Aramaiki sì ní a fi kọ ọ́.