Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strangers: Love of, enjoined

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Love of, enjoined

  1. Ó máa ń gbẹjọ́ aláìní baba àti opó rò, Ó fẹ́ràn àjèjì, Òun fi aṣọ àti oúnjẹ fún wọn.

  2. Ẹ gbọdọ̀ fẹ́ràn àwọn àjèjì, torí pé ẹ̀yin pẹ̀lú ti jẹ́ àjèjì rí ní Ejibiti.