Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Spikenard: An aromatic plant
Àwọn ẹsẹ nípa An aromatic plant
Ohun ọ̀gbìn rẹ àgbàlá pomegiranate ni ti òun ti àṣàyàn èso; kipiresi àti nadi,
nadi àti Safironi, kalamusi àti kinamoni, àti gbogbo igi olóòórùn dídùn, òjìá àti aloe pẹ̀lú irú wọn.