Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Spices: Used in the embalming of Asa

1 ẹsẹ · 9 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Used in the embalming of Asa

  1. wọ́n sì sin ín sínú isà òkú tí ó ti gbẹ́ jáde fún ara rẹ̀ ní ìlú Dafidi. Wọ́n sì tẹ sí orí àkéte tí ó fi òórùn dídùn kún, àti onírúurú tùràrí tí a fi ọgbọ́n pèsè, wọ́n sì da iná ńlá nítorí rẹ̀.