Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sleep: Of the sluggard 2 ẹsẹ · 4 abala Wá "Sleep" Gbogbo 13 A symbol of death 7 Of Jesus 3 Of the sluggard 2 From God 1 Àwọn ẹsẹ nípa Of the sluggard Òwe 6:9Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò dùbúlẹ̀, ìwọ ọ̀lẹ? Nígbà wo ni ìwọ yóò jí kúrò lójú oorun rẹ?Òwe 6:10Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera láti sinmi díẹ̀.