Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shuppim: 1. Son of Ir

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Son of Ir

  1. Àti Ṣuppimu, àti Huppimu, àwọn ọmọ Iri, àti Huṣimu, àwọn ọmọ Aheri.

  2. Makiri sì mú ìyàwó láti àárín àwọn ará Huppimu àti Ṣuppimu. Orúkọ arábìnrin rẹ̀ a máa jẹ́ Maaka. Orúkọ ìran ọmọ mìíràn a máa jẹ́ Selofehadi, tí ó ní àwọn ọmọbìnrin nìkan ṣoṣo.