Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shimrith: Called Shomer

1 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Called Shomer

  1. Àwọn oníṣẹ́ tí ó pa á jẹ́ Josabadi ọmọ Ṣimeati àti Jehosabadi ọmọ Ṣomeri. Ó kú, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú baba rẹ̀ ní ìlú ńlá ti Dafidi. Amasiah ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.