Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shelemiah: 3. Father of Hananiah
Àwọn ẹsẹ nípa 3. Father of Hananiah
Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Hananiah ọmọ Ṣelemiah, àti Hanuni ọmọ ẹ̀kẹfà Salafi, tún apá ibòmíràn ṣe. Lẹ́yìn wọn ni, Meṣullamu ọmọ Berekiah tún ọ̀kánkán òdìkejì ibùgbé ẹ̀ ṣe.