Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Will: The wicked cease not from

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The wicked cease not from

  1. Ṣùgbọ́n ní kété tí onídàájọ́ bá ti kú, àwọn ènìyàn náà a sì tún padà sí ọ̀nà ìbàjẹ́ àní ju ti àwọn baba wọn lọ, wọn a tẹ̀lé òrìṣà, wọ́n ń sìn wọ́n, wọn a sì foríbalẹ̀ fún wọn, wọ́n kọ̀ láti yàgò kúrò ní ọ̀nà ibi wọn àti agídí ọkàn wọn.