Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Scepter: A symbol of authority
Àwọn ẹsẹ nípa A symbol of authority
“Mo rí i, ṣùgbọ́n kì í ṣe ìsinsin yìí. Mo kíyèsi, ṣùgbọ́n kò súnmọ́. Ìràwọ̀ kan yóò jáde láti ọ̀dọ̀ Jakọbu; yóò yọ jáde láti Israẹli. Yóò tẹ̀ fọ́ orí Moabu, yóò sì fọ́ agbárí gbogbo ọmọ Seti.
Olúwa ti dá ọ̀pá ìkà náà, ọ̀pá àwọn aláṣẹ,