Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Saul: 1. Called Shaul, king of Edom

4 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Called Shaul, king of Edom

  1. Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti, létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

  2. Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

  3. Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

  4. Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.