Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sarsechim: A prince of Babylon. Present at the taking of Jerusalem.
Àwọn ẹsẹ nípa A prince of Babylon. Present at the taking of Jerusalem.
Nígbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli wá, wọ́n sì jókòó ní àárín ẹnu ibodè, àní Nergali-Ṣareseri ti Samgari, Nebo-Sarsikimu olórí ìwẹ̀fà, Nergali-Ṣareseri, olórí amòye, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli yóò kú.