Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sardius: In the garden of Eden

1 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In the garden of Eden

  1. Ìwọ ti wà ní Edeni, ọgbà Ọlọ́run; onírúurú òkúta oníyebíye ni ìbora rẹ; sardiu, topasi àti diamọndi, berili, óníkìsì, àti jasperi, safire, emeradi, turikuose, àti karbunkili, àti wúrà, ìpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ àti àwọn òkè rẹ ní a dà, láti ara wúrà, ní ọjọ́ tí á dá ọ ní a pèsè wọn.