Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sardius: In the breastplate

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In the breastplate

  1. Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta oníyebíye mẹ́rin sára ẹsẹ̀ rẹ̀. Ní ẹsẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, topasi àti berili wà;

  2. Ó sì to ipele òkúta oníyebíye mẹ́rin sí i. Ní ipele kìn-ín-ní ní rúbì wà, topasi àti berili;