Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Samson: A judge of Israel

1 ẹsẹ · 12 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A judge of Israel

  1. Nígbà náà ni àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìdílé baba rẹ̀ ní àpapọ̀ gòkè lọ wọ́n sì gbé e, wọ́n gbé e padà wá, wọ́n sì sin ín sí agbede-méjì Sora àti Eṣtaoli, sínú ibojì Manoa baba rẹ̀. Òun ti ṣe àkóso Israẹli ní ogún ọdún.