Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sallu: 1. A Benjamite dwelling in Jerusalem
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A Benjamite dwelling in Jerusalem
Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni: Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah;
Nínú àwọn ìran Benjamini: Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Joẹdi, ọmọ Pedaiah, ọmọ Kolaiah, ọmọ Maaseiah, ọmọ Itieli, ọmọ Jeṣaiah,