Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sackcloth: Animals covered with, at time of national mourning
Àwọn ẹsẹ nípa Animals covered with, at time of national mourning
Ṣùgbọ́n jẹ́ kí ènìyàn àti ẹranko da aṣọ ọ̀fọ̀ bo ara, kí wọn sì kígbe kíkan sí Ọlọ́run, sì jẹ́ kí wọn yípadà, olúkúlùkù kúrò ní ọ̀nà ibi rẹ̀ àti kúrò ní ìwà ìpa tí ó wà lọ́wọ́ wọn.