Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa River: Figurative of grief
Àwọn ẹsẹ nípa Figurative of grief
Omijé sàn jáde ní ojú mi, nítorí wọn kò gba pé òfin rẹ̀ jẹ́ òtítọ́.
Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.