Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rimmon: 5. A Syrian idol

1 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 5. A Syrian idol

  1. Ṣùgbọ́n kí Olúwa kí ó dáríjì ìránṣẹ́ rẹ fún nǹkan yìí. Nígbà tí ọ̀gá mi wọ inú ilé Rimoni láti fi orí balẹ̀ tí ó sì fi ara ti ọwọ́ mi tí mo sì tẹ ara mi ba pẹ̀lú níbẹ̀. Nígbà tí èmi tẹ ara mi ba ní ilé Rimoni, kí Olúwa dáríjì ìránṣẹ́ rẹ fún èyí.”