Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Regicide: Of Joram
Àwọn ẹsẹ nípa Of Joram
Nígbà náà, Jehu fa ọrun rẹ̀, ó sì yin Joramu láàrín èjìká méjèèjì. Ọfà náà sì wọ inú ọkàn rẹ̀, ó sì ṣubú lulẹ̀ láti orí kẹ̀kẹ́ rẹ̀.