Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rab-Mag: An Assyrian prince, or, possibly, a second name given to Nergal-Sharezer.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa An Assyrian prince, or, possibly, a second name given to Nergal-Sharezer.

  1. Nígbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli wá, wọ́n sì jókòó ní àárín ẹnu ibodè, àní Nergali-Ṣareseri ti Samgari, Nebo-Sarsikimu olórí ìwẹ̀fà, Nergali-Ṣareseri, olórí amòye, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli yóò kú.

  2. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú, Nebusaradani balógun ìṣọ́, àti Nebusaradani olórí ìwẹ̀fà, àti Nergali-Ṣareseri, olórí amòye àti gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli,