Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Proverbs: Design of 4 ẹsẹ · 3 abala Wá "Proverbs" Gbogbo 27 Miscellany of 22 Design of 4 Written by Solomon 2 Àwọn ẹsẹ nípa Design of Òwe 1:1Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli.Òwe 1:2Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́, láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀.Òwe 1:3Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo, àti ìdájọ́, àti àìṣègbè;Òwe 1:4láti fi òye fún onírẹ̀lẹ̀, ìmọ̀ àti ìṣọ́ra fún àwọn èwe.