Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Preciousness of Christ: As the source of all grace

2 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa As the source of all grace

  1. Ọ̀rọ̀ náà sì di ara, òun sì ń bá wa gbé. Àwa sì ti rí ògo rẹ̀, àní ògo ọmọ rẹ kan ṣoṣo, tí ó ti ọ̀dọ̀ Baba wá, ó kún fún oore-ọ̀fẹ́ àti òtítọ́.

  2. Nítorí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òun tìkára rẹ̀ lè máa gbé nínú rẹ̀.