Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pound: Equivalent to about twelve ounces

1 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Equivalent to about twelve ounces

  1. Nígbà náà ni Maria mú òróró ìkunra nadi, òsùwọ̀n lita kan, àìlábùlà, olówó iyebíye, ó sì ń fi kun Jesu ní ẹsẹ̀, ó sì ń fi irun orí rẹ̀ nu ẹsẹ̀ rẹ̀ nù. Ilé sì kún fún òórùn ìkunra náà.