Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pelatiah: 2. A Simeonite who was captain in an expedition against the Amalekites

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. A Simeonite who was captain in an expedition against the Amalekites

  1. Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) nínú àwọn ará Simeoni, lábẹ́ ìdarí pẹ̀lú Pelatiah, Neariah, Refaiah àti Usieli, àwọn ọmọ Iṣi, gbógun sí àwọn òkè ìlú ti Seiri.

  2. Wọ́n sì pa àwọn ará Amaleki tí ó kù, àwọn tí ó ti sálà, wọ́n sì ti ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.