Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pekah: Is plotted against and slain by Hoshea

2 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Is plotted against and slain by Hoshea

  1. Nígbà náà, Hosea ọmọ Ela, dìtẹ̀ sí Peka ọmọ Remaliah. Ó dojúkọ ọ́, ó sì pa á, ó sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ogún ọdún Jotamu ọmọ Ussiah.

  2. Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Peka, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Israẹli?