Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pekah: Captain of the army of Israel

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Captain of the army of Israel

  1. Ọ̀kan lára àwọn olórí ìjòyè rẹ̀ Peka ọmọ Remaliah, dìtẹ̀ sí i. Ó mú àádọ́ta àwọn ọkùnrin ti àwọn ará Gileadi pẹ̀lú u rẹ̀. Ó pa Pekahiah pẹ̀lú Argobu àti Arie ní odi ààfin ọba ní Samaria. Bẹ́ẹ̀ ni Peka pa Pekahiah, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.