Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pagiel: Son of Ocran and leader of the tribe of Asher at time of exodus.
Àwọn ẹsẹ nípa Son of Ocran and leader of the tribe of Asher at time of exodus.
Láti ọ̀dọ̀ Aṣeri, Pagieli ọmọ Okanri.
Ẹ̀yà Aṣeri ni yóò pa ibùdó tẹ̀lé wọn. Olórí Aṣeri ni Pagieli ọmọ Okanri.
Pagieli ọmọ Okanri, olórí àwọn ọmọ Aṣeri ni ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kọkànlá.
màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Pagieli ọmọ Okanri.
Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri,