Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Orpah 2 ẹsẹ · 1 abala Wá "Orpah" Gbogbo 2 Daughter-in-law of Naomi. 2 Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Rutu 1:4Wọ́n sì fẹ́ àwọn ọmọbìnrin ará Moabu méjì, orúkọ ọ̀kan ń jẹ́ Oripa, èkejì sì ń jẹ́ Rutu. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n sì ti gbé níbẹ̀ fún bí ọdún mẹ́wàá,Rutu 1:14Wọ́n sì gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì tún sọkún. Nígbà náà ní Oripa fi ẹnu ko ìyá ọkọ rẹ̀ ní ẹnu wí pé ó dìgbà, ṣùgbọ́n Rutu dì mọ́ ọn síbẹ̀.