Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obligation: Acknowledgment of
Àwọn ẹsẹ nípa Acknowledgment of
Kí ni èmi yóò san fún Olúwa nítorí gbogbo rere rẹ̀ sí mi?
Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè èmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa.
Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa ní ojú àwọn ènìyàn rẹ̀.
Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ èmi yóò sì ké pe orúkọ Olúwa.