Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Obadiah: 13. A prophet who prophesied the destruction of Edom
Àwọn ẹsẹ nípa 13. A prophet who prophesied the destruction of Edom
Ìran ti Obadiah. Èyí ni Olúwa Olódùmarè wí nípa Edomu. Àwa ti gbọ́ ohùn kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá, a sì ti rán ikọ̀ kan sí gbogbo kèfèrí láti sọ pé, “Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a dìde ogun sí i.”