Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nile: Called Sihor

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Called Sihor

  1. Láti orí àwọn omi ńlá ni irúgbìn ìyẹ̀fun ti ilẹ̀ Ṣihori ti wá; ìkórè ti odò Naili ni owóòná Tire, òun sì ti di ibùjókòó ọjà fún àwọn orílẹ̀-èdè.

  2. Kí ló dé tí o ṣe wá lọ Ejibiti láti lọ mu omi ní Ṣihori? Kí ló dé tí o sì fi lọ sí Asiria láti lọ mú omi ni odò Eufurate náà?