Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nehushta: Wife of Jehoiakim, king of Judah, and mother of Jehoiachin.
Àwọn ẹsẹ nípa Wife of Jehoiakim, king of Judah, and mother of Jehoiachin.
Jehoiakimu sùn pẹ̀lú baba rẹ̀, Jehoiakini ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
Jehoiakini jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlógún nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún oṣù mẹ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ a sì máa jẹ́ Nehuṣita ọmọbìnrin Elnatani; ó wá láti Jerusalẹmu.