Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Neariah: 1. Son of Shemaiah
Àwọn ẹsẹ nípa 1. Son of Shemaiah
Àwọn ọmọ Ṣekaniah: Ṣemaiah àti àwọn ọmọ rẹ̀: Hattusi, Igali, Bariah, Neariah àti Ṣafati, mẹ́fà ni gbogbo wọn.
Àwọn ọmọ Neariah: Elioenai; Hesekiah, àti Asrikamu, mẹ́ta ni gbogbo wọn.