Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nahath: 2. Called Toah and Tohu. A Levite
Àwọn ẹsẹ nípa 2. Called Toah and Tohu. A Levite
Ọkùnrin kan wà, láti Ramataimu-Sofimu, láti ìlú olókè Efraimu, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elihu, ọmọ Tohu, ọmọ Sufu, ará Efrata.
Elkana ọmọ rẹ̀, Sofai ọmọ rẹ̀ Nahati ọmọ rẹ̀,
ọmọ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elieli, ọmọ Toha,