Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Myrrh: Brought by wise men as a present to Jesus

1 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Brought by wise men as a present to Jesus

  1. Bí wọ́n tí wọ inú ilé náà, wọn rí ọmọ ọwọ́ náà pẹ̀lú Maria ìyá rẹ̀, wọ́n wólẹ̀, wọ́n foríbalẹ̀ fún un. Nígbà náà ni wọ́n tú ìṣúra wọn, wọ́n sì ta Jesu lọ́rẹ: wúrà, tùràrí àti òjìá.