Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Milk: Wealth of the Gentiles
Àwọn ẹsẹ nípa Wealth of the Gentiles
Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè a ó sì fun ọ́ ni ọmú àwọn ọba. Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé, Èmi Olúwa, èmi ni Olùgbàlà rẹ, Olùdáǹdè rẹ, Alágbára ti Jakọbu.