Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meshullam: 4. Three Benjamites
Àwọn ẹsẹ nípa 4. Three Benjamites
Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi
Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni: Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah;
Ibinaiah ọmọ Jerohamu; Ela ọmọ Ussi, ọmọ Mikri; àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ Reueli, ọmọ Ibinijah.