Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meribah: 2. Meribah-kadesh, fountain in the desert of Zin

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. Meribah-kadesh, fountain in the desert of Zin

  1. Èyí ni omi ti Meriba, níbi tí àwọn ọmọ Israẹli ti bá Olúwa jà àti ibi tí O ti fi ara rẹ̀ hàn bí ẹni mímọ́ láàrín wọn.

  2. “Aaroni yóò kú. Kò ní wọ ilẹ̀ tí mo fi fún àwọn ọmọ Israẹli, nítorí ẹ̀yin méjèèjì ṣe àìgbọ́ràn sí òfin mi níbi omi Meriba.