Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mered: Son of Ezra.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Son of Ezra.

  1. Àwọn ọmọ Esra: Jeteri, Meredi, Eferi àti Jaloni. Ọ̀kan lára àwọn aya Meredi sì bí Miriamu, Ṣammai àti Iṣba baba Eṣitemoa.

  2. Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà Juda sì bí Jaredi baba Gedori, àti Heberi baba Soko àti Jekutieli baba Sanoa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin Farao Bitia, ẹni ti Meredi ti fẹ́.