Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Melatiah: A Gibeonite who assisted in repairing the wall of Jerusalem.

1 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A Gibeonite who assisted in repairing the wall of Jerusalem.

  1. Lẹ́yìn in wọn ni àtúnṣe tún wà láti ọ̀dọ̀ àwọn ọkùnrin Gibeoni àti Mispa; Melatiah ti Gibeoni àti Jadoni ti Meronoti; àwọn ibi tí ó wà lábẹ́ àṣẹ baálẹ̀ agbègbè Eufurate.