Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Matthat 2 ẹsẹ · 2 abala Wá "Matthat" Gbogbo 2 1. Father of Heli, and ancestor of Joseph 1 2. Father of Jorim, and ancestor of Joseph 1 Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Luku 3:24tí í ṣe ọmọ Mattati, tí í ṣe ọmọ Lefi, tí í ṣe ọmọ Meliki, tí í ṣe ọmọ Janai, tí í ṣe ọmọ Josẹfu,Luku 3:29tí í ṣe ọmọ Joṣua, tí í ṣe ọmọ Elieseri, tí í ṣe ọmọ Jorimu, tí í ṣe Mattati, tí í ṣe ọmọ Lefi,