Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mattaniah: 3. Son of Heman, who had charge of the ninth division of musicians

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 3. Son of Heman, who had charge of the ninth division of musicians

  1. Gẹ́gẹ́ bí ti Hemani, nínú àwọn ọmọ rẹ̀: Bukkiah, Mattaniah, Usieli, Ṣubaeli àti Jerimoti; Hananiah, Hanani, Eliata, Giddalti, àti Romamtieseri, Joṣbekaṣa, Malloti, Hotiri, Mahasiotu.

  2. ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn-án sí Mattaniah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá